Ìsíkíẹ́lì 11:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Torí náà, sọ pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Èmi yóò mú yín kúrò láàárín àwọn èèyàn, màá kó yín jọ láti àwọn ilẹ̀ tí mo fọ́n yín ká sí, màá sì fún yín ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì.+ Émọ́sì 9:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì tó wà ní ìgbèkùn pa dà,+Wọ́n á tún àwọn ìlú tó ti di ahoro kọ́, wọ́n á sì máa gbé inú wọn;+Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n á sì mu wáìnì wọn,+Wọ́n á ṣe ọgbà, wọ́n á sì jẹ èso wọn.’+
17 “Torí náà, sọ pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Èmi yóò mú yín kúrò láàárín àwọn èèyàn, màá kó yín jọ láti àwọn ilẹ̀ tí mo fọ́n yín ká sí, màá sì fún yín ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì.+
14 Màá kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì tó wà ní ìgbèkùn pa dà,+Wọ́n á tún àwọn ìlú tó ti di ahoro kọ́, wọ́n á sì máa gbé inú wọn;+Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n á sì mu wáìnì wọn,+Wọ́n á ṣe ọgbà, wọ́n á sì jẹ èso wọn.’+