-
2 Kíróníkà 15:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ó kó gbogbo Júdà àti Bẹ́ńjámínì jọ pẹ̀lú àwọn àjèjì tó wà pẹ̀lú wọn tí wọ́n wá láti Éfúrémù àti Mánásè àti Síméónì,+ torí ọ̀pọ̀ wọn ló sá wá sọ́dọ̀ rẹ̀ láti Ísírẹ́lì nígbà tí wọ́n rí i pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀.
-
-
2 Kíróníkà 30:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ṣùgbọ́n, àwọn kan láti Áṣérì, Mánásè àti Sébúlúnì rẹ ara wọn sílẹ̀, wọ́n sì wá sí Jerúsálẹ́mù.+
-