ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 30:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 nígbà náà, Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa mú àwọn èèyàn rẹ tí wọ́n kó lẹ́rú+ pa dà wá, ó máa ṣàánú+ rẹ, ó sì máa kó ọ jọ látọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ tú ọ+ ká sí.

  • Àìsáyà 11:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ó máa gbé àmì* kan sókè fún àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì máa kó àwọn tó fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ,+ ó máa kó àwọn tó tú ká lára Júdà jọ láti ìkángun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé.+

  • Jeremáyà 16:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “‘Síbẹ̀, ìgbà kan ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí, ‘tí wọn ò ní máa sọ pé: “Bí Jèhófà ti wà láàyè, ẹni tó mú àwọn èèyàn Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì!”+ 15 kàkà bẹ́ẹ̀, wọ́n á máa sọ pé: “Bí Jèhófà ti wà láàyè, ẹni tó mú àwọn èèyàn Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ àríwá àti gbogbo ilẹ̀ tó tú wọn ká sí!” màá sì mú wọn pa dà wá sí ilẹ̀ wọn, èyí tí mo fún àwọn baba ńlá wọn.’+

  • Émọ́sì 9:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Màá kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì tó wà ní ìgbèkùn pa dà,+

      Wọ́n á tún àwọn ìlú tó ti di ahoro kọ́, wọ́n á sì máa gbé inú wọn;+

      Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n á sì mu wáìnì wọn,+

      Wọ́n á ṣe ọgbà, wọ́n á sì jẹ èso wọn.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́