-
Ìsíkíẹ́lì 10:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Tí wọ́n bá ń lọ, wọ́n lè lọ sí ibikíbi ní ọ̀nà mẹ́rẹ̀ẹ̀rin láìṣẹ́rí pa dà, torí ibi tí orí bá kọjú sí ni wọ́n máa ń lọ láìṣẹ́rí pa dà.
-