Jòhánù 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Mo ní àwọn àgùntàn mìíràn, tí kò sí lára ọ̀wọ́ yìí;+ mo gbọ́dọ̀ mú àwọn yẹn náà wá, wọ́n á fetí sí ohùn mi, wọ́n á sì di agbo kan, olùṣọ́ àgùntàn kan.+ 1 Pétérù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Tí a bá sì fi olórí olùṣọ́ àgùntàn+ hàn kedere, ẹ máa gba adé ògo tí kì í ṣá.+
16 “Mo ní àwọn àgùntàn mìíràn, tí kò sí lára ọ̀wọ́ yìí;+ mo gbọ́dọ̀ mú àwọn yẹn náà wá, wọ́n á fetí sí ohùn mi, wọ́n á sì di agbo kan, olùṣọ́ àgùntàn kan.+