1 Kíróníkà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ọmọ Hámù ni Kúṣì,+ Mísíráímù, Pútì àti Kénáánì.+