Sekaráyà 14:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Èyí ni àjàkálẹ̀ àrùn tí Jèhófà yóò fi kọ lu gbogbo èèyàn tó bá gbéjà ko Jerúsálẹ́mù:+ Ẹran ara wọn yóò jẹrà lórí ìdúró, ojú wọn yóò jẹrà ní agbárí wọn, ahọ́n wọn yóò sì jẹrà ní ẹnu wọn.
12 “Èyí ni àjàkálẹ̀ àrùn tí Jèhófà yóò fi kọ lu gbogbo èèyàn tó bá gbéjà ko Jerúsálẹ́mù:+ Ẹran ara wọn yóò jẹrà lórí ìdúró, ojú wọn yóò jẹrà ní agbárí wọn, ahọ́n wọn yóò sì jẹrà ní ẹnu wọn.