Jeremáyà 25:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 ‘Ariwo kan á dún títí dé ìkángun ayé,Nítorí Jèhófà ní ẹjọ́ kan pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè. Òun fúnra rẹ̀ á ṣe ìdájọ́ gbogbo àwọn èèyàn.*+ Á sì fi idà pa àwọn ẹni burúkú,’ ni Jèhófà wí.
31 ‘Ariwo kan á dún títí dé ìkángun ayé,Nítorí Jèhófà ní ẹjọ́ kan pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè. Òun fúnra rẹ̀ á ṣe ìdájọ́ gbogbo àwọn èèyàn.*+ Á sì fi idà pa àwọn ẹni burúkú,’ ni Jèhófà wí.