-
Ìsíkíẹ́lì 39:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Tí àwọn tó ń lọ káàkiri ilẹ̀ náà bá rí egungun èèyàn, wọ́n á fi àmì kan sí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀. Àwọn tí wọ́n yàn láti sin òkú yóò wá lọ sin ín sí Àfonífojì Hamoni-Gọ́ọ̀gù.+
-