-
Diutarónómì 31:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Àmọ́ màá fi ojú mi pa mọ́ fún wọn lọ́jọ́ yẹn torí gbogbo ìwà ibi tí wọ́n hù, tí wọ́n lọ ń tọ àwọn ọlọ́run míì lẹ́yìn.+