1 Àwọn Ọba 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó ṣe àwọn fèrèsé* tí férémù wọn fẹ̀ lápá kan tó sì kéré lódìkejì*+ sí ilé náà. Ìsíkíẹ́lì 41:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn fèrèsé tí férémù wọn fẹ̀ lápá kan tó sì kéré lódìkejì*+ àti àwọn àwòrán igi ọ̀pẹ tún wà ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì ibi àbáwọlé* náà àti àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ inú tẹ́ńpìlì àti àwọn ìbòrí náà.
26 Àwọn fèrèsé tí férémù wọn fẹ̀ lápá kan tó sì kéré lódìkejì*+ àti àwọn àwòrán igi ọ̀pẹ tún wà ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì ibi àbáwọlé* náà àti àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ inú tẹ́ńpìlì àti àwọn ìbòrí náà.