-
Ìsíkíẹ́lì 41:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Wọ́n gbẹ́ àwòrán àwọn kérúbù àti igi ọ̀pẹ sára ògiri ibi mímọ́ láti ilẹ̀ dé ibi òkè ẹnu ọ̀nà.