Ìsíkíẹ́lì 44:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Lẹ́yìn náà, ó mú mi gba ẹnubodè àríwá wá sí iwájú tẹ́ńpìlì náà. Nígbà tí mo wò, mo rí i pé ògo Jèhófà kún inú tẹ́ńpìlì Jèhófà.+ Torí náà, mo dojú bolẹ̀.+
4 Lẹ́yìn náà, ó mú mi gba ẹnubodè àríwá wá sí iwájú tẹ́ńpìlì náà. Nígbà tí mo wò, mo rí i pé ògo Jèhófà kún inú tẹ́ńpìlì Jèhófà.+ Torí náà, mo dojú bolẹ̀.+