ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 1:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 “‘Tó bá fẹ́ mú ẹran wá láti fi rú ẹbọ sísun látinú ọ̀wọ́ ẹran, kó jẹ́ akọ tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá.+ Tinútinú+ ni kó mú un wá síwájú Jèhófà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.

  • Léfítíkù 1:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Kí wọ́n bó awọ ẹran náà, kí wọ́n sì gé e sí wẹ́wẹ́.+

  • Léfítíkù 8:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ó gé àgbò náà sí wẹ́wẹ́, Mósè sì mú kí orí àgbò náà, àwọn ègé rẹ̀ àti ọ̀rá rẹ̀ líle* rú èéfín.

  • Ìsíkíẹ́lì 43:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ó wá sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Àwọn ìtọ́ni tí wọ́n á máa tẹ̀ lé tí wọ́n bá ti ṣe pẹpẹ nìyí, kí wọ́n lè máa fi odindi ẹbọ sísun rúbọ lórí rẹ̀, kí wọ́n sì lè máa wọ́n ẹ̀jẹ̀ sórí rẹ̀.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́