2 Sámúẹ́lì 17:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kódà ẹ̀rù á ba ọkùnrin tó láyà bíi kìnnìún,+ ọkàn rẹ̀ á sì domi, torí gbogbo Ísírẹ́lì ló mọ̀ pé akíkanjú ni bàbá rẹ+ àti pé àwọn ọkùnrin tó wà pẹ̀lú rẹ̀ ní ìgboyà. Òwe 28:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ẹni burúkú ń sá nígbà tí ẹnì kankan kò lé e,Àmọ́ olódodo láyà bíi kìnnìún.*+
10 Kódà ẹ̀rù á ba ọkùnrin tó láyà bíi kìnnìún,+ ọkàn rẹ̀ á sì domi, torí gbogbo Ísírẹ́lì ló mọ̀ pé akíkanjú ni bàbá rẹ+ àti pé àwọn ọkùnrin tó wà pẹ̀lú rẹ̀ ní ìgboyà.