ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 6:12, 13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Kí iná máa jó lórí pẹpẹ. Kò gbọ́dọ̀ kú. Kí àlùfáà máa dáná igi  + lórí rẹ̀ láràárọ̀, kó to ẹbọ sísun sórí rẹ̀, kó sì mú kí ọ̀rá ẹbọ ìrẹ́pọ̀ rú èéfín lórí rẹ̀.+ 13 Iná gbọ́dọ̀ máa jó lórí pẹpẹ náà nígbà gbogbo. Kò gbọ́dọ̀ kú.

  • Nọ́ńbà 18:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Kí ẹ máa ṣe ojúṣe yín tó jẹ mọ́ ibi mímọ́ + àti pẹpẹ,+ kí n má bàa tún bínú+ sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

  • 2 Kíróníkà 13:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ní tiwa, Jèhófà ni Ọlọ́run wa,+ a kò sì fi í sílẹ̀; àwọn àlùfáà wa, ìyẹn àtọmọdọ́mọ Áárónì ń ṣe ìránṣẹ́ fún Jèhófà, àwọn ọmọ Léfì sì ń ṣèrànwọ́ lẹ́nu iṣẹ́ náà. 11 Wọ́n ń mú àwọn ẹbọ sísun rú èéfín sí Jèhófà ní àràárọ̀ àti ní ìrọ̀lẹ́-ìrọ̀lẹ́+ pẹ̀lú tùràrí onílọ́fínńdà,+ àwọn búrẹ́dì onípele*+ sì wà lórí tábìlì ògidì wúrà, wọ́n máa ń tan ọ̀pá fìtílà wúrà+ àti àwọn fìtílà rẹ̀ ní alaalẹ́,+ nítorí pé à ń ṣe ojúṣe wa fún Jèhófà Ọlọ́run wa; àmọ́ ẹ̀yin ti fi í sílẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́