1 Àwọn Ọba 7:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó ṣe àwọn òpó ibi àbáwọlé* tẹ́ńpìlì.*+ Ó ṣe òpó apá ọ̀tún,* ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jákínì,* lẹ́yìn náà, ó ṣe òpó apá òsì,* ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Bóásì.*+
21 Ó ṣe àwọn òpó ibi àbáwọlé* tẹ́ńpìlì.*+ Ó ṣe òpó apá ọ̀tún,* ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jákínì,* lẹ́yìn náà, ó ṣe òpó apá òsì,* ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Bóásì.*+