1 Àwọn Ọba 6:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó fi àwọn pátákó kédárì bo* àwọn ògiri inú ilé náà. Ó fi àwọn ẹ̀là gẹdú bo ògiri inú, láti ìsàlẹ̀ ilé náà títí dé àwọn igi ìrólé tó wà ní àjà, ó sì fi àwọn pátákó júnípà+ bo ilẹ̀ ilé náà. 2 Kíróníkà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó fi igi júnípà bo ilé ńlá náà, lẹ́yìn náà, ó fi wúrà tó dára bò ó,+ ó wá ya àwòrán igi ọ̀pẹ+ àti ẹ̀wọ̀n+ sára rẹ̀.
15 Ó fi àwọn pátákó kédárì bo* àwọn ògiri inú ilé náà. Ó fi àwọn ẹ̀là gẹdú bo ògiri inú, láti ìsàlẹ̀ ilé náà títí dé àwọn igi ìrólé tó wà ní àjà, ó sì fi àwọn pátákó júnípà+ bo ilẹ̀ ilé náà.
5 Ó fi igi júnípà bo ilé ńlá náà, lẹ́yìn náà, ó fi wúrà tó dára bò ó,+ ó wá ya àwòrán igi ọ̀pẹ+ àti ẹ̀wọ̀n+ sára rẹ̀.