Ìsíkíẹ́lì 44:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 ‘Àwọn ni yóò wọnú ibi mímọ́ mi, wọ́n á wá síbi tábìlì mi kí wọ́n lè ṣiṣẹ́ fún mi,+ wọ́n á sì bójú tó iṣẹ́ tó yẹ kí wọ́n ṣe fún mi.+ Málákì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “‘Ẹ̀ ń fi oúnjẹ* ẹlẹ́gbin rúbọ lórí pẹpẹ mi.’ “‘Ẹ sì sọ pé: “Kí la ṣe tí a fi sọ ẹ́ di ẹlẹ́gbin?”’ “‘Ẹ̀ ń sọ pé: “Tábìlì Jèhófà+ kò wúlò.”
16 ‘Àwọn ni yóò wọnú ibi mímọ́ mi, wọ́n á wá síbi tábìlì mi kí wọ́n lè ṣiṣẹ́ fún mi,+ wọ́n á sì bójú tó iṣẹ́ tó yẹ kí wọ́n ṣe fún mi.+
7 “‘Ẹ̀ ń fi oúnjẹ* ẹlẹ́gbin rúbọ lórí pẹpẹ mi.’ “‘Ẹ sì sọ pé: “Kí la ṣe tí a fi sọ ẹ́ di ẹlẹ́gbin?”’ “‘Ẹ̀ ń sọ pé: “Tábìlì Jèhófà+ kò wúlò.”