Ìsíkíẹ́lì 40:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nínú àwọn ìran tí Ọlọ́run fi hàn mí, ó mú mi wá sí ilẹ̀ Ísírẹ́lì, ó sì gbé mi sórí òkè kan tó ga fíofío.+ Ohun kan wà lórí òkè náà tó dà bí ìlú kan ní apá gúúsù.
2 Nínú àwọn ìran tí Ọlọ́run fi hàn mí, ó mú mi wá sí ilẹ̀ Ísírẹ́lì, ó sì gbé mi sórí òkè kan tó ga fíofío.+ Ohun kan wà lórí òkè náà tó dà bí ìlú kan ní apá gúúsù.