-
Ìsíkíẹ́lì 40:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ó wá sí ẹnubodè tó kọjú sí ìlà oòrùn,+ ó sì gun àtẹ̀gùn tó wà níbẹ̀. Nígbà tó wọn ẹnubodè náà, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ọ̀pá esùsú kan, fífẹ̀ ẹnu ọ̀nà kejì náà sì jẹ́ ọ̀pá esùsú kan.
-