Ìsíkíẹ́lì 9:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ wá gbéra lórí àwọn kérúbù níbi tó wà tẹ́lẹ̀, lọ sí ẹnu ọ̀nà ilé náà,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í pe ọkùnrin tó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ náà, tí ìwo yíǹkì akọ̀wé wà ní ìbàdí rẹ̀. Ìsíkíẹ́lì 11:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ògo Jèhófà + wá gbéra kúrò ní ìlú náà, ó sì dúró lórí òkè tó wà ní ìlà oòrùn ìlú náà.+
3 Ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ wá gbéra lórí àwọn kérúbù níbi tó wà tẹ́lẹ̀, lọ sí ẹnu ọ̀nà ilé náà,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í pe ọkùnrin tó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ náà, tí ìwo yíǹkì akọ̀wé wà ní ìbàdí rẹ̀.