7 Màá mú kí àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì mọ orúkọ mímọ́ mi, mi ò sì tún ní jẹ́ kí wọ́n kó ẹ̀gàn bá orúkọ mímọ́ mi mọ́; àwọn orílẹ̀-èdè á sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,+ Ẹni Mímọ́ ní Ísírẹ́lì.’+
2 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ní ọjọ́ yẹn, èmi yóò pa orúkọ àwọn òrìṣà rẹ́ ní ilẹ̀ náà,+ wọn ò sì ní rántí wọn mọ́; èmi yóò sì mú àwọn wòlíì+ àti ẹ̀mí àìmọ́ kúrò ní ilẹ̀ náà.