Ìsíkíẹ́lì 44:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà wá sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, fiyè sílẹ̀,* la ojú rẹ sílẹ̀, kí o sì fetí sílẹ̀ dáadáa sí gbogbo ohun tí mo bá sọ fún ọ nípa àwọn ìlànà àti òfin tẹ́ńpìlì Jèhófà. Fiyè sí ẹnu ọ̀nà àbáwọlé tẹ́ńpìlì náà dáadáa àti gbogbo ọ̀nà àbájáde ibi mímọ́.+
5 Jèhófà wá sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, fiyè sílẹ̀,* la ojú rẹ sílẹ̀, kí o sì fetí sílẹ̀ dáadáa sí gbogbo ohun tí mo bá sọ fún ọ nípa àwọn ìlànà àti òfin tẹ́ńpìlì Jèhófà. Fiyè sí ẹnu ọ̀nà àbáwọlé tẹ́ńpìlì náà dáadáa àti gbogbo ọ̀nà àbájáde ibi mímọ́.+