Ẹ́kísódù 27:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí o ṣe ìwo+ sí igun rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin; àwọn ìwo náà yóò wà lára pẹpẹ náà, kí o sì fi bàbà bo pẹpẹ náà.+ Ìfihàn 9:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Áńgẹ́lì kẹfà+ fun kàkàkí rẹ̀.+ Mo sì gbọ́ ohùn kan, ó wá látinú àwọn ìwo tó wà lórí pẹpẹ, èyí tí wọ́n fi wúrà ṣe+ tó wà níwájú Ọlọ́run,
2 Kí o ṣe ìwo+ sí igun rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin; àwọn ìwo náà yóò wà lára pẹpẹ náà, kí o sì fi bàbà bo pẹpẹ náà.+
13 Áńgẹ́lì kẹfà+ fun kàkàkí rẹ̀.+ Mo sì gbọ́ ohùn kan, ó wá látinú àwọn ìwo tó wà lórí pẹpẹ, èyí tí wọ́n fi wúrà ṣe+ tó wà níwájú Ọlọ́run,