-
Ẹ́kísódù 29:36, 37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Kí o máa fi akọ màlúù tó wà fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ rúbọ lójoojúmọ́ láti fi ṣe ètùtù, kí o sì ṣe ètùtù fún pẹpẹ náà láti wẹ ẹ̀ṣẹ̀ kúrò lára rẹ̀, kí o sì fòróró yàn án láti sọ ọ́ di mímọ́.+ 37 Ọjọ́ méje ni kí o fi ṣe ètùtù fún pẹpẹ náà, kí o sì sọ ọ́ di mímọ́ kó lè di pẹpẹ mímọ́ jù lọ.+ Ẹnikẹ́ni tó bá fara kan pẹpẹ náà ti gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́.
-
-
Léfítíkù 8:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Mósè pa á, ó fi ìka rẹ̀ mú ẹ̀jẹ̀ ẹran náà,+ ó fi sára àwọn ìwo tó wà ní gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ, ó sì wẹ ẹ̀ṣẹ̀ kúrò lára pẹpẹ náà, àmọ́ ó da ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ, kó lè yà á sí mímọ́ láti ṣe ètùtù lórí rẹ̀.
-