Ẹ́kísódù 29:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 “Gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ yìí ni kí o ṣe fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀. Ọjọ́ méje ni kí o lò láti sọ wọ́n di àlùfáà.*+
35 “Gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ yìí ni kí o ṣe fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀. Ọjọ́ méje ni kí o lò láti sọ wọ́n di àlùfáà.*+