Ẹ́kísódù 28:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 “Kí o tún ṣe aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ àti ọ̀já fún àwọn ọmọ Áárónì+ pẹ̀lú aṣọ tí wọ́n máa wé sórí, kí wọ́n lè ní ògo àti ẹwà.+ Ẹ́kísódù 28:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Kí o tún fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe ṣòkòtò péńpé* fún wọn kó lè bo ìhòòhò wọn.+ Kó gùn láti ìbàdí dé itan.
40 “Kí o tún ṣe aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ àti ọ̀já fún àwọn ọmọ Áárónì+ pẹ̀lú aṣọ tí wọ́n máa wé sórí, kí wọ́n lè ní ògo àti ẹwà.+