-
Ìsíkíẹ́lì 42:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Tí àwọn àlùfáà bá wọlé, kí wọ́n má ṣe jáde kúrò ní ibi mímọ́ lọ sí àgbàlá ìta láìkọ́kọ́ bọ́ aṣọ tí wọ́n fi ṣiṣẹ́,+ torí aṣọ mímọ́ ni. Wọ́n á wọ aṣọ míì kí wọ́n tó sún mọ́ ibi tí àwọn èèyàn lè dé.”
-