Léfítíkù 21:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Sọ fún àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Áárónì pé, ‘Ẹnikẹ́ni nínú yín ò gbọ́dọ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́ torí ẹni* tó kú láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.+ Léfítíkù 21:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí wọ́n má ṣe fá orí wọn,+ kí wọ́n má sì fá eteetí irùngbọ̀n wọn tàbí kí wọ́n fi nǹkan ya ara wọn.+ Diutarónómì 14:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Ọmọ Jèhófà Ọlọ́run yín lẹ jẹ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ kọ ara yín ní abẹ+ tàbí kí ẹ fá iwájú orí yín* torí òkú.+
21 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Sọ fún àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Áárónì pé, ‘Ẹnikẹ́ni nínú yín ò gbọ́dọ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́ torí ẹni* tó kú láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.+
5 Kí wọ́n má ṣe fá orí wọn,+ kí wọ́n má sì fá eteetí irùngbọ̀n wọn tàbí kí wọ́n fi nǹkan ya ara wọn.+
14 “Ọmọ Jèhófà Ọlọ́run yín lẹ jẹ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ kọ ara yín ní abẹ+ tàbí kí ẹ fá iwájú orí yín* torí òkú.+