-
Ìsíkíẹ́lì 47:21, 22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Kí ẹ pín ilẹ̀ yìí láàárín ara yín, láàárín ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì. 22 Kí ẹ pín in kó jẹ́ ogún láàárín ara yín àti láàárín àwọn àjèjì tó ń gbé pẹ̀lú yín tí wọ́n sì ti bímọ nígbà tí wọ́n ń gbé pẹ̀lú yín; bí ọmọ Ísírẹ́lì ni wọ́n á jẹ́ sí yín. Àwọn náà yóò rí ogún gbà bíi tiyín láàárín àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì.
-