-
Ìsíkíẹ́lì 48:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “Nítòsí ilẹ̀ àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì yóò ní ilẹ̀ kan tí gígùn rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́, tí fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́. (Gbogbo rẹ̀ yóò jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n [25,000] ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, fífẹ̀ rẹ̀ yóò sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá [10,000] ìgbọ̀nwọ́.)
-