Ìsíkíẹ́lì 44:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́, ìjòyè yóò jókòó síbẹ̀ kó lè jẹ oúnjẹ níwájú Jèhófà,+ torí ìjòyè ni. Yóò gba ibi àbáwọlé* ẹnubodè náà wọlé, ibẹ̀ sì ni yóò gbà jáde.”+
3 Àmọ́, ìjòyè yóò jókòó síbẹ̀ kó lè jẹ oúnjẹ níwájú Jèhófà,+ torí ìjòyè ni. Yóò gba ibi àbáwọlé* ẹnubodè náà wọlé, ibẹ̀ sì ni yóò gbà jáde.”+