17 Àmọ́ ìjòyè náà ló máa mú odindi ẹbọ sísun,+ ọrẹ ọkà+ àti ọrẹ ohun mímu wá nígbà àwọn àjọ̀dún,+ ọjọ́ òṣùpá tuntun, àwọn Sábáàtì+ àti ní gbogbo àjọ̀dún tí ilé Ísírẹ́lì máa ń ṣe.+ Òun ló máa pèsè ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, ọrẹ ọkà, odindi ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀, láti ṣe ètùtù torí ilé Ísírẹ́lì.’