2 Kíróníkà 35:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n se* ẹran Ìrékọjá lórí iná gẹ́gẹ́ bí àṣà;+ wọ́n sì se àwọn ẹran mímọ́ nínú àwọn ìkòkò àti àwọn ìkòkò irin pẹ̀lú àwọn páànù, lẹ́yìn náà, wọ́n gbé e wá kíákíá fún gbogbo ìyókù àwọn èèyàn náà.
13 Wọ́n se* ẹran Ìrékọjá lórí iná gẹ́gẹ́ bí àṣà;+ wọ́n sì se àwọn ẹran mímọ́ nínú àwọn ìkòkò àti àwọn ìkòkò irin pẹ̀lú àwọn páànù, lẹ́yìn náà, wọ́n gbé e wá kíákíá fún gbogbo ìyókù àwọn èèyàn náà.