-
Jóṣúà 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé.
-
-
Jóṣúà 15:62Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
62 Níbúṣánì, Ìlú Iyọ̀ àti Ẹ́ń-gédì,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́fà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-