Ìsíkíẹ́lì 10:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn* ní ojú mẹ́rin. Ojú àkọ́kọ́ jẹ́ ojú kérúbù, ojú kejì jẹ́ ojú èèyàn, ojú kẹta jẹ́ ojú kìnnìún, ojú kẹrin sì jẹ́ ojú idì.+ 15 Àwọn kérúbù náà á sì dìde, àwọn ni ẹ̀dá alààyè* tí mo rí ní odò Kébárì,+ Ìfihàn 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ̀dá alààyè àkọ́kọ́ dà bíi kìnnìún,+ ẹ̀dá alààyè kejì dà bí akọ ọmọ màlúù,+ ẹ̀dá alààyè kẹta+ ní ojú bíi ti èèyàn, ẹ̀dá alààyè kẹrin+ sì dà bí ẹyẹ idì tó ń fò.+
14 Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn* ní ojú mẹ́rin. Ojú àkọ́kọ́ jẹ́ ojú kérúbù, ojú kejì jẹ́ ojú èèyàn, ojú kẹta jẹ́ ojú kìnnìún, ojú kẹrin sì jẹ́ ojú idì.+ 15 Àwọn kérúbù náà á sì dìde, àwọn ni ẹ̀dá alààyè* tí mo rí ní odò Kébárì,+
7 Ẹ̀dá alààyè àkọ́kọ́ dà bíi kìnnìún,+ ẹ̀dá alààyè kejì dà bí akọ ọmọ màlúù,+ ẹ̀dá alààyè kẹta+ ní ojú bíi ti èèyàn, ẹ̀dá alààyè kẹrin+ sì dà bí ẹyẹ idì tó ń fò.+