-
Ìsíkíẹ́lì 47:15-17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Ààlà ilẹ̀ náà ní apá àríwá nìyí: Ó lọ láti Òkun Ńlá títí lọ dé Hẹ́tílónì,+ sí ọ̀nà Sédádì,+ 16 Hámátì,+ Bérótà+ àti Síbúráímù, tó wà láàárín agbègbè Damásíkù àti Hámátì, ó dé Haseri-hátíkónì, tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ààlà Háúránì.+ 17 Ààlà náà yóò jẹ́ láti òkun dé Hasari-énónì,+ lẹ́bàá ààlà Damásíkù sí àríwá àti ààlà Hámátì.+ Ààlà tó wà ní àríwá nìyí.
-