-
Ìsíkíẹ́lì 45:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Látinú ibi tí ẹ wọ̀n yìí ni kí ẹ ti wọn ibi tó jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, tí fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́, inú rẹ̀ ni ibi mímọ́ yóò wà, ohun mímọ́ jù lọ. 4 Ibẹ̀ ló máa jẹ́ ibi mímọ́ nínú ilẹ̀ náà, yóò jẹ́ ti àwọn àlùfáà,+ àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ní ibi mímọ́, tó ń wá síwájú Jèhófà láti ṣiṣẹ́ fún un.+ Ibẹ̀ ni ilé wọn máa wà, ibẹ̀ ló sì máa jẹ́ ibi mímọ́ fún tẹ́ńpìlì náà.
-