-
Ìsíkíẹ́lì 48:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ìwọ̀n ìlú náà nìyí: Ààlà tó wà ní àríwá jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ọgọ́rùn-ún márùn-ún (4,500) ìgbọ̀nwọ́, ti gúúsù jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ọgọ́rùn-ún márùn-ún (4,500) ìgbọ̀nwọ́, ti ìlà oòrùn jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ọgọ́rùn-ún márùn-ún (4,500) ìgbọ̀nwọ́, ti ìwọ̀ oòrùn sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ọgọ́rùn-ún márùn-ún (4,500) ìgbọ̀nwọ́.
-