Sáàmù 103:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin áńgẹ́lì rẹ̀,+ tí ẹ jẹ́ alágbára ńlá,Tí ẹ̀ ń ṣe ohun tó sọ,+ tí ẹ sì ń fetí sí ohùn rẹ̀.* Hébérù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bákan náà, ó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì pé: “Ó dá àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mí, ó sì dá àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀*+ ní ọwọ́ iná.”+ Hébérù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ṣebí ẹ̀mí tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́*+ ni gbogbo wọn, tí a rán jáde láti ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn tó máa rí ìgbàlà?
20 Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin áńgẹ́lì rẹ̀,+ tí ẹ jẹ́ alágbára ńlá,Tí ẹ̀ ń ṣe ohun tó sọ,+ tí ẹ sì ń fetí sí ohùn rẹ̀.*
7 Bákan náà, ó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì pé: “Ó dá àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mí, ó sì dá àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀*+ ní ọwọ́ iná.”+
14 Ṣebí ẹ̀mí tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́*+ ni gbogbo wọn, tí a rán jáde láti ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn tó máa rí ìgbàlà?