ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 22:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ní ọdún kejìdínlógún Ọba Jòsáyà, ọba rán Ṣáfánì akọ̀wé tó jẹ́ ọmọ Asaláyà ọmọ Méṣúlámù sí ilé Jèhófà,+ ó ní: 4 “Lọ bá Hilikáyà+ àlùfáà àgbà, ní kó gba gbogbo owó tí wọ́n mú wá sí ilé Jèhófà+ jọ, èyí tí àwọn aṣọ́nà gbà lọ́wọ́ àwọn èèyàn náà.+

  • 2 Àwọn Ọba 25:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Nebukadinésárì ọba Bábílónì yan Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ṣe olórí àwọn èèyàn tí ó fi sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà.+

  • Jeremáyà 26:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Àmọ́ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ran Jeremáyà lọ́wọ́, kí wọ́n má bàa fi í lé àwọn èèyàn náà lọ́wọ́ láti pa á.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́