-
Ìsíkíẹ́lì 10:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Bí mo ṣe ń wò, mo rí ohun tó rí bí òkúta sàfáyà lókè ohun tó tẹ́ pẹrẹsẹ lórí àwọn kérúbù náà, ó sì dà bí ìtẹ́.+