15Nígbà náà, Jèhófà sọ fún mi pé: “Bí Mósè àti Sámúẹ́lì bá tiẹ̀ dúró níwájú mi,+ mi ò ní ṣojúure sí* àwọn èèyàn yìí. Lé wọn kúrò níwájú mi, kí wọ́n máa lọ.
9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+