Ìsíkíẹ́lì 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọkàn* tó bá ṣẹ̀ ni yóò kú.+ Ọmọ ò ní ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ bàbá rẹ̀, bàbá ò sì ní ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ rẹ̀. Olódodo máa jèrè òdodo rẹ̀, ẹni burúkú sì máa jèrè ìwà burúkú rẹ̀.+ Sefanáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+
20 Ọkàn* tó bá ṣẹ̀ ni yóò kú.+ Ọmọ ò ní ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ bàbá rẹ̀, bàbá ò sì ní ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ rẹ̀. Olódodo máa jèrè òdodo rẹ̀, ẹni burúkú sì máa jèrè ìwà burúkú rẹ̀.+
3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+