-
Jeremáyà 23:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “Mo ti rí ohun ìríra nínú àwọn wòlíì Samáríà.+
Báálì ló ń mú kí wọ́n lè sọ àsọtẹ́lẹ̀,
Wọ́n sì ń kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì ṣìnà.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 23:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ìwọ yóò mu àmuyó, ìbànújẹ́ yóò sì bò ọ́,
Wàá mu látinú ife ìbẹ̀rù àti ti ahoro,
Ife Samáríà ẹ̀gbọ́n rẹ.
-