Jeremáyà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́, gbára dì,*Kí o sì dìde láti bá wọn sọ gbogbo ohun tí mo bá pa láṣẹ fún ọ. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù wọn bà ọ́,+Kí n má bàa jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́ níwájú wọn.
17 Àmọ́, gbára dì,*Kí o sì dìde láti bá wọn sọ gbogbo ohun tí mo bá pa láṣẹ fún ọ. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù wọn bà ọ́,+Kí n má bàa jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́ níwájú wọn.