Málákì 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní tòótọ́, ọrẹ tí Júdà àti Jerúsálẹ́mù bá mú wá yóò mú inú Jèhófà dùn,* bíi ti àtijọ́ àti àwọn ọdún láéláé.+
4 Ní tòótọ́, ọrẹ tí Júdà àti Jerúsálẹ́mù bá mú wá yóò mú inú Jèhófà dùn,* bíi ti àtijọ́ àti àwọn ọdún láéláé.+