Ẹ́kísódù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+ Sáàmù 97:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìkùukùu àti ìṣúdùdù tó kàmàmà yí i ká;+Òtítọ́ àti ìdájọ́ òdodo ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ̀.+ 3 Iná ń lọ níwájú rẹ̀,+Ó sì ń jó àwọn ọ̀tá rẹ̀ run yí ká.+
18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+
2 Ìkùukùu àti ìṣúdùdù tó kàmàmà yí i ká;+Òtítọ́ àti ìdájọ́ òdodo ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ̀.+ 3 Iná ń lọ níwájú rẹ̀,+Ó sì ń jó àwọn ọ̀tá rẹ̀ run yí ká.+