Léfítíkù 19:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 “‘Ẹ gbọ́dọ̀ máa pa àwọn sábáàtì mi mọ́,+ kí ẹ sì máa bọ̀wọ̀ fún* ibi mímọ́ mi. Èmi ni Jèhófà.